Tope Alabi – Logan Ti Ode ft. TY Bello x George

0

Download another hot clean mp3 audio song lyrics by Tope Alabi and this amazing music is titled “Logan Ti Ode” ft. TY Bello x George.

On her Spontaneous Worship series, this one remains just as powerful and spirit moving as the rest. Logan Ti Ode is a song that ministers about God’s Instant healing, Blessing and wonders immediately He intervene.

The song was produced by George.

 

Listen up below!.

 

DOWNLOAD MP3

 

 

[Lyrics]

 

Emi mo oun oju mi tiri

Mo mo oun eti mi ti gbo

Mo oun oju mi tiri

Mo mo oun eti mi ti gbo

Logan to gbo iro Ayo re o Olugbala

Aiye mi le to

Logan to gbo iro Ayo re o Olugbala

Aiye mi le to

Mo mo oun aiye ma ti wi

Mo mo oun eyan ma ti so

Won ti pe wa ni agan ri

Boya won ti pewa lo’olosi ri

Sugbon, Logan ti o de o Olugbala, aye e le to

Sugbon, Logan ti o de o Olugbala, aye e le to

Aye to ti daru tele tele o

Logan ti o de

Oro ti eniyan ti fi s’alufani re

Logan ti o de

Oro ti ko dara ta ti so si o

Logan ti o de

Oruko ti kin se tire ta ti pe o

Logan ti o de

Ani logan ti o de o Olugbala aye e le to

Logan ti o de o Olugbala

Aye e le to

Logan ti Jesu de o Olugbala

L’aye e le to

Ko s’oruko t’aye o le pe ni

Wa ma peni l’agan l’ona gbo gbo

Bo ba lowo lowo agan n

Bo ba bi mo o agan ni

Bo ba tegba ko dagba agan lo je

Sugbon logan ti o de

Sope logan ti o de

Ani logan ti o de, lesekese

Logan ti o de

Ahah, logan ti o de o Olugbala

L’aye e le to

Logan ti o de o Olugbala

L’aye e le to

Instantly lo’n je be

Bo se n debe

Won de yi oruko pada

Logan ti o de, eheheh logan ti o de

Eyin ta pe l’agan e ma so wi pe

Logan ti o de

Awon ta ti fi oruko aburu pe ni’le won yi

Logan ti o de

Ani logan ti o de o Olugbala, l’aye mi le to

Logan ti o de o Olugbala

L’aye mi le to

Ani eheh, logan ti o de o Olugbala

L’aye mi le to

Ani, logan ti o de o aseda

L’aye mi le to

Ani, logan ti o de o Olorun o

L’aye mi le to

Irawo owuro omo Mary yo sinu oro mi, l’aye mi le to

Ah, alagbara ni Shiloh loba ran ti mi si rere, l’aye mi le to

Enu mi wa kun fu eri o gbogbo, l’aye mi le to

Aye mi gba iyipada otun o logan to de, l’aye mi le to

Aye mi ba leto l’ota ba wo Iran mi, l’aye mi le to

Aye mi le to lo ta bawo Iran mi, l’aye mi le to

Ota kaworo, enu won gbe tan lori oju kan, l’aye mi le to

Ahah, logan ti o de o Olugbala, l’aye mi le to

Thank you Lord Jesus for all you’ve done

You might also like
Leave A Reply

Your email address will not be published.